4 Nígbà tí Saulu gbọ́ pé Dafidi ti sá àsálà lọ sí Gati, ó dẹ́kun láti máa wá a kiri.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 27
Wo Samuẹli Kinni 27:4 ni o tọ