Samuẹli Kinni 30:10 BM

10 Dafidi ati irinwo (400) eniyan sì ń lépa wọn lọ, ṣugbọn àwọn igba (200) eniyan tí àárẹ̀ mú kò lè la odò náà kọjá, wọ́n sì dúró sí etí odò.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:10 ni o tọ