11 Wọ́n gba àpótí ẹ̀rí Ọlọrun lọ́wọ́ àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n sì pa Hofini ati Finehasi, àwọn ọmọ Eli mejeeji.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4
Wo Samuẹli Kinni 4:11 ni o tọ