Samuẹli Kinni 4:12 BM

12 Ọkunrin kan láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini, ti ojú ogun sáré pada lọ sí Ṣilo, ó sì dé ibẹ̀ lọ́jọ́ náà. Ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì ku erùpẹ̀ sórí láti fi ìbànújẹ́ rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:12 ni o tọ