Samuẹli Kinni 7:1 BM

1 Àwọn ará ìlú Kiriati Jearimu wá, wọ́n gbé àpótí OLUWA náà lọ sí ilé Abinadabu, tí ń gbé orí òkè kan. Wọ́n ya Eleasari, ọmọ rẹ̀ sí mímọ́, láti máa bojútó àpótí OLUWA náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7

Wo Samuẹli Kinni 7:1 ni o tọ