2 Láti ìgbà náà, Kiriati Jearimu ni wọ́n gbé àpótí OLUWA sí fún nǹkan bíi ogún ọdún, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sì ń ké pe OLUWA fún ìrànlọ́wọ́.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7
Wo Samuẹli Kinni 7:2 ni o tọ