25 Nígbà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá sinu ìlú láti ibi ìrúbọ náà, wọ́n tẹ́ ibùsùn kan fún Saulu lórí òrùlé, ó sì sùn sibẹ.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9
Wo Samuẹli Kinni 9:25 ni o tọ