26 Nígbà tí ó di àfẹ̀mọ́júmọ́, Samuẹli pe Saulu lórí òrùlé, ó ní, “Dìde kí n sìn ọ́ sọ́nà.” Saulu dìde, òun ati Samuẹli bá jáde sí òpópónà.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9
Wo Samuẹli Kinni 9:26 ni o tọ