40 Wọ́n a máa jẹ ilé àwọn opó run. Wọ́n a máa gbadura gígùn nítorí àṣehàn. Ìdájọ́ tí wọn yóo gbà yóo le pupọ.”
Ka pipe ipin Maku 12
Wo Maku 12:40 ni o tọ