Maku 14:10 BM

10 Judasi Iskariotu, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila, bá lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn olórí alufaa, ó lọ fi Jesu lé wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:10 ni o tọ