Maku 14:40 BM

40 Ó tún wá, ó rí i pé wọ́n tún ń sùn, nítorí pé oorun ń kùn wọ́n pupọ. Wọn kò wá mọ ìdáhùn tí wọn ì bá fi fún un mọ́.

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:40 ni o tọ