Maku 14:45 BM

45 Lẹsẹkẹsẹ bí ó ti dé, Judasi lọ sí ọ̀dọ̀ Jesu, ó kí i, ó ní, “Olùkọ́ni!” Ó sì da ẹnu dé e ní ẹ̀rẹ̀kẹ́.

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:45 ni o tọ