Maku 14:5 BM

5 Bí a bá tà á, ìbá tó nǹkan bí ọọdunrun (300) owó fadaka, à bá sì fún àwọn talaka.” Báyìí ni wọ́n ń fi ohùn líle bá obinrin náà wí.

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:5 ni o tọ