Maku 14:62 BM

62 Jesu dáhùn pé, “Èmi ni. Ẹ óo rí Ọmọ-Eniyan tí ó jókòó lórí ìtẹ́ pẹlu agbára Ọlọrun, tí ìkùukùu yóo sì máa gbé e bọ̀ wá.”

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:62 ni o tọ