Maku 4:34 BM

34 Kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láì lo òwe. Ṣugbọn nígbà tí ó bá ku òun ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, a máa túmọ̀ gbogbo rẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:34 ni o tọ