Maku 4:7 BM

7 Irúgbìn mìíràn bọ́ sí orí ilẹ̀ ẹlẹ́gùn-ún. Nígbà tí ẹ̀gún dàgbà, ó fún wọn pa, nítorí náà wọn kò so èso.

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:7 ni o tọ