Maku 6:30 BM

30 Àwọn aposteli Jesu pé jọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n ròyìn gbogbo nǹkan tí wọ́n ti ṣe ati bí wọ́n ti kọ́ àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:30 ni o tọ