Maku 6:55 BM

55 Wọ́n bá ń súré láti gbogbo àdúgbò ibẹ̀, wọ́n ń gbé àwọn aláìsàn wọn lórí ibùsùn wá sí ibikíbi tí wọn bá gbọ́ pé Jesu wà.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:55 ni o tọ