Maku 7:27 BM

27 Jesu wí fún un pé, “Jẹ́ kí àwọn ọmọ rí oúnjẹ jẹ yó ná, nítorí kò dára kí á mú oúnjẹ ọmọ kí á sọ ọ́ fún ajá.”

Ka pipe ipin Maku 7

Wo Maku 7:27 ni o tọ