15 Batṣeba si tọ̀ ọba lọ ni iyẹ̀wu: ọba si gbó gidigidi: Abiṣagi, ara Ṣunemu, si nṣe iranṣẹ fun ọba.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1
Wo 1. A. Ọba 1:15 ni o tọ