1. A. Ọba 1:19 YCE

19 O si pa malu ati ẹran ti o li ọra, ati agùtan li ọ̀pọlọpọ, o si pe gbogbo awọn ọmọ ọba, ati Abiatari alufa, ati Joabu balogun: ṣugbọn Solomoni iranṣẹ rẹ ni kò pè.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1

Wo 1. A. Ọba 1:19 ni o tọ