1. A. Ọba 1:2 YCE

2 Awọn iranṣẹ rẹ̀ si wi fun u pe, Jẹ ki a wá ọmọbinrin kan, wundia, fun Oluwa mi, ọba: ki o si duro niwaju ọba, ki o si ṣikẹ́ rẹ̀, ki o si dubulẹ li õkan-aiya rẹ̀, oluwa mi, ọba yio si mõru.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1

Wo 1. A. Ọba 1:2 ni o tọ