35 Ki ẹ si goke tọ̀ ọ lẹhin, ki o si wá, ki o si joko lori itẹ mi; on o si jọba ni ipò mi: emi si pa a laṣẹ lati jẹ olori Israeli ati Juda.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1
Wo 1. A. Ọba 1:35 ni o tọ