37 Bi Oluwa ti wà pẹlu oluwa mi ọba, gẹgẹ bẹ̃ni ki o wà pẹlu Solomoni, ki o si ṣe itẹ rẹ̀ ki o pọ̀ jù itẹ oluwa mi, Dafidi ọba lọ.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1
Wo 1. A. Ọba 1:37 ni o tọ