1. A. Ọba 1:41 YCE

41 Ati Adonijah ati gbogbo awọn ti o pè sọdọ rẹ̀ si gbọ́, nigbati nwọn jẹun tan, Joabu si gbọ́ iró ipè o si wipe: eredi ariwo ilu ti nrọkẹkẹ yi?

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1

Wo 1. A. Ọba 1:41 ni o tọ