45 Sadoku, alufa ati Natani, woli si ti fi ororo yàn a li ọba ni Gihoni: nwọn si fi ayọ̀ goke lati ibẹ wá, tobẹ̃ ti ilu si nho. Eyi ni ariwo ti ẹ ti gbọ́.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1
Wo 1. A. Ọba 1:45 ni o tọ