1. A. Ọba 10:5 YCE

5 Ati onjẹ tabili rẹ̀, ati ijoko awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀, ati iduro awọn iranṣẹ rẹ̀, ati iwọṣọ wọn, ati awọn agbọti rẹ̀, ati ọna ti o mba goke lọ si ile Oluwa; kò kù agbara kan fun u mọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 10

Wo 1. A. Ọba 10:5 ni o tọ