1. A. Ọba 11:18 YCE

18 Nwọn si dide kuro ni Midiani, nwọn si wá si Parani; nwọn si mu enia pẹlu wọn lati Parani wá: nwọn si wá si Egipti, sọdọ Farao ọba Egipti, o si fun u ni ile kan, o si yàn onjẹ fun u, o si fun u ni ilẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:18 ni o tọ