1. A. Ọba 11:29 YCE

29 O si ṣe li àkoko na, nigbati Jeroboamu jade kuro ni Jerusalemu, woli Ahijah ara Ṣilo ri i loju ọ̀na; o si wọ̀ agbáda titun; awọn meji pere li o si mbẹ ni oko:

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:29 ni o tọ