1. A. Ọba 11:34 YCE

34 Ṣugbọn emi kì yio gba gbogbo ijọba na lọwọ rẹ̀, ṣugbọn emi o ṣe e li ọmọ-alade ni gbogbo ọjọ aiye rẹ̀, nitori Dafidi, iranṣẹ mi, ẹniti mo yàn, nitori o ti pa ofin mi ati aṣẹ mi mọ́:

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:34 ni o tọ