1. A. Ọba 12:14 YCE

14 O si sọ fun wọn gẹgẹ bi ìmọran awọn ipẹrẹ wipe, Baba mi mu ki àjaga nyin ki o wuwo, emi o si bù kún àjaga nyin: baba mi fi paṣan nà nyin, ṣugbọn akẽke li emi o fi nà nyin,

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 12

Wo 1. A. Ọba 12:14 ni o tọ