1. A. Ọba 12:33 YCE

33 O si gun ori pẹpẹ na lọ ti o ti ṣe ni Beteli li ọjọ kẹdogun oṣu kẹjọ, li oṣu ti o rò li ọkàn ara rẹ̀; o si da àse silẹ fun awọn ọmọ Israeli; o si gun ori pẹpẹ na lọ, lati fi turari jona.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 12

Wo 1. A. Ọba 12:33 ni o tọ