1. A. Ọba 12:6 YCE

6 Rehoboamu ọba si ba awọn àgbagba, ti imã duro niwaju Solomoni, baba rẹ̀, nigbati o wà lãye, gbimọ̀ wipe, Imọran kili ẹnyin dá, ki emi ki o lè da awọn enia yi lohùn?

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 12

Wo 1. A. Ọba 12:6 ni o tọ