1. A. Ọba 12:8 YCE

8 Ṣugbọn o kọ̀ ìmọran awọn àgbagba ti nwọn ba a dá, o si ba awọn ipẹrẹ ti nwọn dagba pẹlu rẹ̀, ti nwọn si duro niwaju rẹ̀ gbimọ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 12

Wo 1. A. Ọba 12:8 ni o tọ