14 O si tẹ̀le enia Ọlọrun na lẹhin, o si ri i, o joko labẹ igi nla kan: o si wi fun u pe, Iwọ enia Ọlọrun na ti o ti Juda wá? On si wipe, Emi ni.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13
Wo 1. A. Ọba 13:14 ni o tọ