1. A. Ọba 13:3 YCE

3 O si fun wọn li àmi kan li ọjọ kanna wipe, Eyi li àmi ti Oluwa ti ṣe; Kiyesi i, pẹpẹ na yio ya, ẽru ti mbẹ lori rẹ̀ yio si danu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:3 ni o tọ