1. A. Ọba 14:7 YCE

7 Lọ, sọ fun Jeroboamu, pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli wi, Nitori bi mo ti gbé ọ ga lati inu awọn enia, ti mo si fi ọ jẹ olori Israeli enia mi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 14

Wo 1. A. Ọba 14:7 ni o tọ