1. A. Ọba 15:24 YCE

24 Asa si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi baba rẹ̀. Jehoṣafati, ọmọ rẹ̀, si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 15

Wo 1. A. Ọba 15:24 ni o tọ