1. A. Ọba 16:13 YCE

13 Nitori gbogbo ẹ̀ṣẹ Baaṣa, ati Ela, ọmọ rẹ̀, nipa eyiti nwọn ṣẹ̀, ati nipa eyiti nwọn mu Israeli ṣẹ̀, ni fifi ohun-asán wọn wọnnì mu ki Oluwa, Ọlọrun Israeli binu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:13 ni o tọ