1. A. Ọba 16:16 YCE

16 Awọn enia ti o dotì gbọ́ wipe, Simri ditẹ̀ o si ti pa ọba pẹlu: nitorina gbogbo Israeli fi Omri, olori ogun, jẹ ọba lori Israeli li ọjọ na ni ibudo.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:16 ni o tọ