1. A. Ọba 16:19 YCE

19 Nitori ẹ̀ṣẹ rẹ̀ wọnni ti o da, ni ṣiṣe buburu niwaju Oluwa, ni rirìn li ọ̀na Jeroboamu ati ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀ ti o da, lati mu ki Israeli ki o ṣẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:19 ni o tọ