1. A. Ọba 16:26 YCE

26 Nitori ti o rìn ni gbogbo ọ̀na Jeroboamu, ọmọ Nebati, ati ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀, eyiti o mu Israeli ṣẹ̀, lati fi ohun-asán wọn wọnni mu Oluwa, Ọlọrun Israeli binu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:26 ni o tọ