1. A. Ọba 16:28 YCE

28 Omri si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i ni Samaria: Ahabu ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:28 ni o tọ