1. A. Ọba 16:30 YCE

30 Ahabu, ọmọ Omri, si ṣe buburu li oju Oluwa jù gbogbo awọn ti o wà ṣaju rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:30 ni o tọ