1. A. Ọba 16:33 YCE

33 Ahabu si ṣe ere oriṣa kan; Ahabu si ṣe jù gbogbo awọn ọba Israeli lọ, ti o wà ṣaju rẹ̀, lati mu ki Oluwa Ọlọrun Israeli binu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 16

Wo 1. A. Ọba 16:33 ni o tọ