1. A. Ọba 18:30 YCE

30 Njẹ Elijah wi fun gbogbo awọn enia na pe, Ẹ sunmọ mi. Gbogbo awọn enia na si sunmọ ọ. On si tun pẹpẹ Oluwa ti o ti wo lulẹ ṣe.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:30 ni o tọ