1. A. Ọba 18:7 YCE

7 Nigbati Obadiah si wà li ọ̀na, kiyesi i, Elijah pade rẹ̀: nigbati o mọ̀ ọ, o si doju rẹ̀ bolẹ, o si wipe, Ṣé iwọ oluwa mi Elijah nìyí?

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:7 ni o tọ