15 Oluwa si wi fun u pe, Lọ, pada li ọ̀na rẹ, kọja li aginju si Damasku: nigbati iwọ ba de ibẹ, ki o si fi ororo yan Hasaeli li ọba lori Siria.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 19
Wo 1. A. Ọba 19:15 ni o tọ