1. A. Ọba 19:4 YCE

4 Ṣugbọn on tikararẹ̀ lọ ni irin ọjọ kan si aginju, o si wá, o si joko labẹ igi juniperi kan, o si tọrọ fun ara rẹ̀ ki on ba le kú; o si wipe, O to; nisisiyi, Oluwa, gba ẹmi mi kuro nitori emi kò sàn jù awọn baba mi lọ!

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 19

Wo 1. A. Ọba 19:4 ni o tọ