9 O si de ibẹ̀, si ibi ihò okuta, o si wọ̀ sibẹ, si kiyesi i, ọ̀rọ Oluwa tọ̀ ọ wá, o si wi fun u pe, Kini iwọ nṣe nihinyi, Elijah?
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 19
Wo 1. A. Ọba 19:9 ni o tọ